Font Size
Johanu 7:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 7:31
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
31 (A)Ọ̀pọ̀ nínú ìjọ ènìyàn sì gbà á gbọ́, wọ́n sì wí pé, “Nígbà tí Kristi náà bá dé, yóò ha ṣe iṣẹ́ ààmì jù wọ̀nyí, tí ọkùnrin yìí ti ṣe lọ?”
Read full chapter
Johanu 10:42
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 10:42
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
42 (A)Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ sì gbà á gbọ́.
Read full chapter
Johanu 11:45
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Johanu 11:45
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Àwọn alábojútó pinnu láti pa Jesu
45 Nítorí náà ni ọ̀pọ̀ àwọn Júù tí ó wá sọ́dọ̀ Maria, tí wọ́n rí ohun tí Jesu ṣe, ṣe gbà á gbọ́.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.