Font Size
Jobu 1:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jobu 1:6
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìdánwò Jobu àkọ́kọ́
6 Ǹjẹ́ ó di ọjọ́ kan, nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run wá í pé níwájú Olúwa, Satani sì wá pẹ̀lú wọn.
Read full chapter
Jobu 2:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Jobu 2:1
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn
Ìdánwò Jobu lẹ́ẹ̀kejì
2 Ó sì tún di ọjọ́ kan nígbà tí àwọn ọmọ Ọlọ́run wá síwájú Olúwa, Satani sì wá pẹ̀lú wọn láti pe níwájú Olúwa.
Read full chapter
Bíbélì Mímọ́ Yorùbá Òde Òn (BYO)
Copyright: Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde-Òní Ẹ̀tọ́ àdàkọ © 2009, 2017 by Biblica, Inc. A lò ó nípa ìgbàyọ̀ǹda láti ọwọ́ Bíbílíkà Inc. Ààbò lórí ẹ̀tọ́ àdàkọ yìí múlẹ̀ jákèjádò àgbáyé. Yoruba Contemporary Bible Copyright © 2009, 2017 by Biblica, Inc.® Used by permission of Biblica, Inc.® All rights reserved worldwide.